Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 23 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿وَإِنَّا لَنَحۡنُ نُحۡيِۦ وَنُمِيتُ وَنَحۡنُ ٱلۡوَٰرِثُونَ ﴾
[الحِجر: 23]
﴿وإنا لنحن نحيي ونميت ونحن الوارثون﴾ [الحِجر: 23]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa, Àwa mà l’À ń sọ (ẹ̀dá) di alààyè. A sì ń sọ ọ́ di òkú. Àwa sì ni A óò jogún (ẹ̀dá) |