Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 24 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿وَلَقَدۡ عَلِمۡنَا ٱلۡمُسۡتَقۡدِمِينَ مِنكُمۡ وَلَقَدۡ عَلِمۡنَا ٱلۡمُسۡتَـٔۡخِرِينَ ﴾
[الحِجر: 24]
﴿ولقد علمنا المستقدمين منكم ولقد علمنا المستأخرين﴾ [الحِجر: 24]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé dájúdájú A mọ àwọn olùgbawájú nínú yín. Dájúdájú A sì mọ àwọn olùgbẹ̀yìn |