Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 29 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿فَإِذَا سَوَّيۡتُهُۥ وَنَفَخۡتُ فِيهِ مِن رُّوحِي فَقَعُواْ لَهُۥ سَٰجِدِينَ ﴾
[الحِجر: 29]
﴿فإذا سويته ونفخت فيه من روحي فقعوا له ساجدين﴾ [الحِجر: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí Mo bá ṣe é t’ó gún régé tán, tí Mo fẹ́ ẹ̀mí sí i (lára) nínú ẹ̀mí Mi (tí Mo dá), nígbà náà ẹ dojú bolẹ̀ fún un ní olùforíkanlẹ̀-kíni |