Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 41 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿قَالَ هَٰذَا صِرَٰطٌ عَلَيَّ مُسۡتَقِيمٌ ﴾
[الحِجر: 41]
﴿قال هذا صراط علي مستقيم﴾ [الحِجر: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Allāhu) sọ pé: "(Ìdúróṣinṣin lójú) ọ̀nà tààrà, Ọwọ́ Mi ni èyí wà |