Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 42 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿إِنَّ عِبَادِي لَيۡسَ لَكَ عَلَيۡهِمۡ سُلۡطَٰنٌ إِلَّا مَنِ ٱتَّبَعَكَ مِنَ ٱلۡغَاوِينَ ﴾
[الحِجر: 42]
﴿إن عبادي ليس لك عليهم سلطان إلا من اتبعك من الغاوين﴾ [الحِجر: 42]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn ẹrúsìn Mi, kò sí agbára kan fún ọ lórí wọn, àyàfi ẹni tí ó bá tẹ̀lé ọ nínú àwọn ẹni anù |