Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 56 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿قَالَ وَمَن يَقۡنَطُ مِن رَّحۡمَةِ رَبِّهِۦٓ إِلَّا ٱلضَّآلُّونَ ﴾
[الحِجر: 56]
﴿قال ومن يقنط من رحمة ربه إلا الضالون﴾ [الحِجر: 56]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: “Kò mà sí ẹni tí ó máa jákànmùná nínú ìkẹ́ Olúwa Rẹ̀ bí kò ṣe àwọn olùṣìnà.” |