Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 55 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿قَالُواْ بَشَّرۡنَٰكَ بِٱلۡحَقِّ فَلَا تَكُن مِّنَ ٱلۡقَٰنِطِينَ ﴾
[الحِجر: 55]
﴿قالوا بشرناك بالحق فلا تكن من القانطين﴾ [الحِجر: 55]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: “À ń fún ọ ní ìró ìdùnnú pẹ̀lú òdodo. Nítorí náà, má ṣe wà lára àwọn olùjákànmùná.” |