Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 9 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿إِنَّا نَحۡنُ نَزَّلۡنَا ٱلذِّكۡرَ وَإِنَّا لَهُۥ لَحَٰفِظُونَ ﴾
[الحِجر: 9]
﴿إنا نحن نـزلنا الذكر وإنا له لحافظون﴾ [الحِجر: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa l’A sọ Tírà Ìrántí kalẹ̀ (ìyẹn al-Ƙur’ān). Dájúdájú Àwa sì ni Olùṣọ́ rẹ̀ |