Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 8 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿مَا نُنَزِّلُ ٱلۡمَلَٰٓئِكَةَ إِلَّا بِٱلۡحَقِّ وَمَا كَانُوٓاْ إِذٗا مُّنظَرِينَ ﴾
[الحِجر: 8]
﴿ما ننـزل الملائكة إلا بالحق وما كانوا إذا منظرين﴾ [الحِجر: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A ò níí sọ mọlāika kalẹ̀ bí kò ṣe pẹ̀lú òdodo. Wọn kò sì níí lọ́ wọn lára mọ́ nígbà náà (tí àwọn mọlāika bá sọ̀kalẹ̀) |