Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 121 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿شَاكِرٗا لِّأَنۡعُمِهِۚ ٱجۡتَبَىٰهُ وَهَدَىٰهُ إِلَىٰ صِرَٰطٖ مُّسۡتَقِيمٖ ﴾
[النَّحل: 121]
﴿شاكرا لأنعمه اجتباه وهداه إلى صراط مستقيم﴾ [النَّحل: 121]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó máa ń dúpẹ́ àwọn ìdẹ̀ra Allāhu. Allāhu ṣà á lẹ́ṣà. Ó sì tọ́ ọ sí ọ̀nà tààrà (’Islām) |