Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 122 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿وَءَاتَيۡنَٰهُ فِي ٱلدُّنۡيَا حَسَنَةٗۖ وَإِنَّهُۥ فِي ٱلۡأٓخِرَةِ لَمِنَ ٱلصَّٰلِحِينَ ﴾
[النَّحل: 122]
﴿وآتيناه في الدنيا حسنة وإنه في الآخرة لمن الصالحين﴾ [النَّحل: 122]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A ṣe ohun rere fún un nílé ayé. Àti pé ní ọ̀run dájúdájú ó máa wà nínú àwọn ẹni rere |