Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 128 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿إِنَّ ٱللَّهَ مَعَ ٱلَّذِينَ ٱتَّقَواْ وَّٱلَّذِينَ هُم مُّحۡسِنُونَ ﴾
[النَّحل: 128]
﴿إن الله مع الذين اتقوا والذين هم محسنون﴾ [النَّحل: 128]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Allāhu wà pẹ̀lú àwọn t’ó bẹ̀rù (Rẹ̀) àti àwọn t’ó ń ṣe rere |