Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 46 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿أَوۡ يَأۡخُذَهُمۡ فِي تَقَلُّبِهِمۡ فَمَا هُم بِمُعۡجِزِينَ ﴾
[النَّحل: 46]
﴿أو يأخذهم في تقلبهم فما هم بمعجزين﴾ [النَّحل: 46]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí (Allāhu) kò lè gbá wọn mú lórí ìrìnkè-rindò wọn ni? Wọn kò sì níí mórí bọ́ |