Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 47 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿أَوۡ يَأۡخُذَهُمۡ عَلَىٰ تَخَوُّفٖ فَإِنَّ رَبَّكُمۡ لَرَءُوفٞ رَّحِيمٌ ﴾
[النَّحل: 47]
﴿أو يأخذهم على تخوف فإن ربكم لرءوف رحيم﴾ [النَّحل: 47]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí (Allāhu) kò lè máa gbá wọn mú díẹ̀díẹ̀ ni? Nítorí náà, dájúdájú Olúwa yin má ni Aláàánú, Oníkẹ̀ẹ́ |