Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 22 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿لَّا تَجۡعَلۡ مَعَ ٱللَّهِ إِلَٰهًا ءَاخَرَ فَتَقۡعُدَ مَذۡمُومٗا مَّخۡذُولٗا ﴾
[الإسرَاء: 22]
﴿لا تجعل مع الله إلها آخر فتقعد مذموما مخذولا﴾ [الإسرَاء: 22]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Má ṣe mú ọlọ́hun mìíràn mọ́ Allāhu nítorí kí o má baà jókòó (sínú Iná) ní ẹni àbùkù, ẹni tí wọ́n máa dá ìṣòro rẹ̀ dá |