Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 23 - الكَهف - Page - Juz 15
﴿وَلَا تَقُولَنَّ لِشَاْيۡءٍ إِنِّي فَاعِلٞ ذَٰلِكَ غَدًا ﴾
[الكَهف: 23]
﴿ولا تقولن لشيء إني فاعل ذلك غدا﴾ [الكَهف: 23]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Má ṣe sọ nípa kiní kan pé: “Dájúdájú èmi yóò ṣe ìyẹn ní ọ̀la.” |