Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 83 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿أَلَمۡ تَرَ أَنَّآ أَرۡسَلۡنَا ٱلشَّيَٰطِينَ عَلَى ٱلۡكَٰفِرِينَ تَؤُزُّهُمۡ أَزّٗا ﴾
[مَريَم: 83]
﴿ألم تر أنا أرسلنا الشياطين على الكافرين تؤزهم أزا﴾ [مَريَم: 83]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé o ò rí i pé dájúdájú Àwa ń rán àwọn èṣù sí àwọn aláìgbàgbọ́ ni, tí wọ́n sì ń tì wọ́n ní ìtìkutì (síbi ẹ̀ṣẹ̀) |