Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 84 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿فَلَا تَعۡجَلۡ عَلَيۡهِمۡۖ إِنَّمَا نَعُدُّ لَهُمۡ عَدّٗا ﴾
[مَريَم: 84]
﴿فلا تعجل عليهم إنما نعد لهم عدا﴾ [مَريَم: 84]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, má ṣe kánjú nípa (ìyà) wọn. A kúkú ń ka (ọjọ́) fún wọn ní kíkà tààrà |