Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 86 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَنَسُوقُ ٱلۡمُجۡرِمِينَ إِلَىٰ جَهَنَّمَ وِرۡدٗا ﴾
[مَريَم: 86]
﴿ونسوق المجرمين إلى جهنم وردا﴾ [مَريَم: 86]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A sì máa da àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ lọ sínú iná Jahanamọ wìtìwìtì |