Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 87 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿لَّا يَمۡلِكُونَ ٱلشَّفَٰعَةَ إِلَّا مَنِ ٱتَّخَذَ عِندَ ٱلرَّحۡمَٰنِ عَهۡدٗا ﴾
[مَريَم: 87]
﴿لا يملكون الشفاعة إلا من اتخذ عند الرحمن عهدا﴾ [مَريَم: 87]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn kò níí ní ìkápá ìṣìpẹ̀ àfi ẹni tí ó bá gba àdéhùn láti ọ̀dọ̀ Àjọkẹ́-ayé |