Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 85 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿يَوۡمَ نَحۡشُرُ ٱلۡمُتَّقِينَ إِلَى ٱلرَّحۡمَٰنِ وَفۡدٗا ﴾
[مَريَم: 85]
﴿يوم نحشر المتقين إلى الرحمن وفدا﴾ [مَريَم: 85]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Rántí) ọjọ́ tí A óò kó àwọn olùbẹ̀rù (Allāhu) jọ sọ́dọ̀ Àjọkẹ́-ayé lórí n̄ǹkan ìgùn |