Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 90 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿تَكَادُ ٱلسَّمَٰوَٰتُ يَتَفَطَّرۡنَ مِنۡهُ وَتَنشَقُّ ٱلۡأَرۡضُ وَتَخِرُّ ٱلۡجِبَالُ هَدًّا ﴾
[مَريَم: 90]
﴿تكاد السموات يتفطرن منه وتنشق الأرض وتخر الجبال هدا﴾ [مَريَم: 90]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn sánmọ̀ fẹ́rẹ̀ fàya pẹ́rẹpẹ̀rẹ nítorí rẹ̀, ilẹ̀ fẹ́rẹ̀ fàya pẹ́rẹpẹ̀rẹ, àwọn àpáta sì fẹ́rẹ̀ dà wó lulẹ̀ gbì |