Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 227 - البَقَرَة - Page - Juz 2
﴿وَإِنۡ عَزَمُواْ ٱلطَّلَٰقَ فَإِنَّ ٱللَّهَ سَمِيعٌ عَلِيمٞ ﴾
[البَقَرَة: 227]
﴿وإن عزموا الطلاق فإن الله سميع عليم﴾ [البَقَرَة: 227]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí wọ́n bá sì pinnu ìkọ̀sílẹ̀, (kí wọ́n kọ̀ wọ́n sílẹ̀.) Dájúdájú Allāhu ni Olùgbọ́, Onímọ̀ |