Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 21 - طه - Page - Juz 16
﴿قَالَ خُذۡهَا وَلَا تَخَفۡۖ سَنُعِيدُهَا سِيرَتَهَا ٱلۡأُولَىٰ ﴾
[طه: 21]
﴿قال خذها ولا تخف سنعيدها سيرتها الأولى﴾ [طه: 21]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Allāhu) sọ pé: "Mú un dání, má sì ṣe bẹ̀rù. A máa dá a padà sí ìrísí rẹ̀ àkọ́kọ́ |