Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 46 - طه - Page - Juz 16
﴿قَالَ لَا تَخَافَآۖ إِنَّنِي مَعَكُمَآ أَسۡمَعُ وَأَرَىٰ ﴾
[طه: 46]
﴿قال لا تخافا إنني معكما أسمع وأرى﴾ [طه: 46]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Allāhu) sọ pé: “Ẹ má ṣe páyà. Dájúdájú Èmi wà pẹ̀lú ẹ̀yin méjèèjì; Mò ń gbọ (yín), Mo sì ń ri (yín).” |