Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 45 - طه - Page - Juz 16
﴿قَالَا رَبَّنَآ إِنَّنَا نَخَافُ أَن يَفۡرُطَ عَلَيۡنَآ أَوۡ أَن يَطۡغَىٰ ﴾
[طه: 45]
﴿قالا ربنا إننا نخاف أن يفرط علينا أو أن يطغى﴾ [طه: 45]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn méjèèjì sọ pé: “Olúwa wa, dájúdájú àwa ń páyà pé ó má yára jẹ wá níyà tàbí pé ó má tayọ ẹnu-àlà.” |