Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 51 - طه - Page - Juz 16
﴿قَالَ فَمَا بَالُ ٱلۡقُرُونِ ٱلۡأُولَىٰ ﴾
[طه: 51]
﴿قال فما بال القرون الأولى﴾ [طه: 51]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Fir‘aon) wí pé: “Kí l’ó mú àwọn ìran àkọ́kọ́ (tí wọn kò fi mọ̀nà)?” |