Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 101 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ سَبَقَتۡ لَهُم مِّنَّا ٱلۡحُسۡنَىٰٓ أُوْلَٰٓئِكَ عَنۡهَا مُبۡعَدُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 101]
﴿إن الذين سبقت لهم منا الحسنى أولئك عنها مبعدون﴾ [الأنبيَاء: 101]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn tí rere ti ṣíwájú fún láti ọ̀dọ̀ Wa, àwọn wọ̀nyẹn ni A óò gbé jìnnà sí Iná |