Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 21 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿أَمِ ٱتَّخَذُوٓاْ ءَالِهَةٗ مِّنَ ٱلۡأَرۡضِ هُمۡ يُنشِرُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 21]
﴿أم اتخذوا آلهة من الأرض هم ينشرون﴾ [الأنبيَاء: 21]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí wọ́n ní àwọn ọlọ́hun kan tí wọ́n mú jáde láti ara ilẹ̀, tí wọ́n ń jí òkú dìde ni |