Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 20 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿يُسَبِّحُونَ ٱلَّيۡلَ وَٱلنَّهَارَ لَا يَفۡتُرُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 20]
﴿يسبحون الليل والنهار لا يفترون﴾ [الأنبيَاء: 20]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n ń ṣàfọ̀mọ́ ní òru àti ní ọ̀sán; kò sì rẹ̀ wọ́n |