Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 55 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿قَالُوٓاْ أَجِئۡتَنَا بِٱلۡحَقِّ أَمۡ أَنتَ مِنَ ٱللَّٰعِبِينَ ﴾
[الأنبيَاء: 55]
﴿قالوا أجئتنا بالحق أم أنت من اللاعبين﴾ [الأنبيَاء: 55]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: “Ṣé o mú òdodo wá fún wa ni tàbí ìwọ wà lára àwọn ẹlẹ́fẹ̀.” |