Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 54 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿قَالَ لَقَدۡ كُنتُمۡ أَنتُمۡ وَءَابَآؤُكُمۡ فِي ضَلَٰلٖ مُّبِينٖ ﴾
[الأنبيَاء: 54]
﴿قال لقد كنتم أنتم وآباؤكم في ضلال مبين﴾ [الأنبيَاء: 54]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: “Dájúdájú ẹ̀yin àti àwọn bàbá yín ti wà nínú ìṣìnà pọ́nńbélé.” |