Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 105 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿أَلَمۡ تَكُنۡ ءَايَٰتِي تُتۡلَىٰ عَلَيۡكُمۡ فَكُنتُم بِهَا تُكَذِّبُونَ ﴾
[المؤمنُون: 105]
﴿ألم تكن آياتي تتلى عليكم فكنتم بها تكذبون﴾ [المؤمنُون: 105]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé wọ́n kì í ka àwọn āyah Mi fun yín ni, àmọ́ tí ẹ̀ ń pè é nírọ́ |