Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 106 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿قَالُواْ رَبَّنَا غَلَبَتۡ عَلَيۡنَا شِقۡوَتُنَا وَكُنَّا قَوۡمٗا ضَآلِّينَ ﴾
[المؤمنُون: 106]
﴿قالوا ربنا غلبت علينا شقوتنا وكنا قوما ضالين﴾ [المؤمنُون: 106]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: "Olúwa wa, orí burúkú l’ó kọlù wá; àwa sì jẹ́ ìjọ olùṣìnà |