Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 114 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿قَٰلَ إِن لَّبِثۡتُمۡ إِلَّا قَلِيلٗاۖ لَّوۡ أَنَّكُمۡ كُنتُمۡ تَعۡلَمُونَ ﴾
[المؤمنُون: 114]
﴿قال إن لبثتم إلا قليلا لو أنكم كنتم تعلمون﴾ [المؤمنُون: 114]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Allāhu) sọ pé: “Ẹ kò gbé ilé ayé bí kò ṣe fún ìgbà díẹ̀, tí ó bá jẹ́ pé ẹ mọ̀.” |