Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 92 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿عَٰلِمِ ٱلۡغَيۡبِ وَٱلشَّهَٰدَةِ فَتَعَٰلَىٰ عَمَّا يُشۡرِكُونَ ﴾
[المؤمنُون: 92]
﴿عالم الغيب والشهادة فتعالى عما يشركون﴾ [المؤمنُون: 92]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Allāhu) Onímọ̀-ìkọ̀kọ̀ àti gban̄gba. Nítorí náà, Ó ga tayọ n̄ǹkan tí wọ́n fi ń ṣẹbọ sí I |