Quran with Yoruba translation - Surah An-Nur ayat 49 - النور - Page - Juz 18
﴿وَإِن يَكُن لَّهُمُ ٱلۡحَقُّ يَأۡتُوٓاْ إِلَيۡهِ مُذۡعِنِينَ ﴾
[النور: 49]
﴿وإن يكن لهم الحق يأتوا إليه مذعنين﴾ [النور: 49]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí ó bá sì jẹ́ pé àwọn ni wọ́n ni ẹ̀tọ́ (àre) ni, wọn yóò wá bá ọ ní tọkàn-tara |