Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 25 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿وَيَوۡمَ تَشَقَّقُ ٱلسَّمَآءُ بِٱلۡغَمَٰمِ وَنُزِّلَ ٱلۡمَلَٰٓئِكَةُ تَنزِيلًا ﴾
[الفُرقَان: 25]
﴿ويوم تشقق السماء بالغمام ونـزل الملائكة تنـزيلا﴾ [الفُرقَان: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé (rántí) ọjọ́ tí sánmọ̀ yó fàya pẹ̀lú àwọn ẹ̀ṣújò funfun. A sì máa sọ àwọn mọlāika kalẹ̀ tààrà |