Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 24 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿أَصۡحَٰبُ ٱلۡجَنَّةِ يَوۡمَئِذٍ خَيۡرٞ مُّسۡتَقَرّٗا وَأَحۡسَنُ مَقِيلٗا ﴾
[الفُرقَان: 24]
﴿أصحاب الجنة يومئذ خير مستقرا وأحسن مقيلا﴾ [الفُرقَان: 24]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn èrò inú Ọgbà Ìdẹ̀ra, ní ọjọ́ yẹn, (ọgbà wọn) máa lóore jùlọ ní ibùgbé. Ó sì máa dára jùlọ ní ibùsinmi |