Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 26 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿ٱلۡمُلۡكُ يَوۡمَئِذٍ ٱلۡحَقُّ لِلرَّحۡمَٰنِۚ وَكَانَ يَوۡمًا عَلَى ٱلۡكَٰفِرِينَ عَسِيرٗا ﴾
[الفُرقَان: 26]
﴿الملك يومئذ الحق للرحمن وكان يوما على الكافرين عسيرا﴾ [الفُرقَان: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìjọba òdodo ti ọjọ́ yẹn ń jẹ́ ti Àjọkẹ́-ayé. Ó sì jẹ́ ọjọ́ kan tí ó máa nira fún àwọn aláìgbàgbọ́ |