Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 46 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿ثُمَّ قَبَضۡنَٰهُ إِلَيۡنَا قَبۡضٗا يَسِيرٗا ﴾
[الفُرقَان: 46]
﴿ثم قبضناه إلينا قبضا يسيرا﴾ [الفُرقَان: 46]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, A (fi ìmọ́lẹ̀ òòrùn) mú òkùnkùn (kúrò níta) wá sí ọ̀dọ̀ Wa ní mímú díẹ̀díẹ̀ (kí ojúmọ́ lè mọ́) |