Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 113 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿إِنۡ حِسَابُهُمۡ إِلَّا عَلَىٰ رَبِّيۖ لَوۡ تَشۡعُرُونَ ﴾
[الشعراء: 113]
﴿إن حسابهم إلا على ربي لو تشعرون﴾ [الشعراء: 113]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò sí ìṣírò-iṣẹ́ wọn lọ́dọ̀ ẹnì kan bí kò ṣe lọ́dọ̀ Olúwa mi, tí ó bá jẹ́ pé ẹ bá fura |