Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 157 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿فَعَقَرُوهَا فَأَصۡبَحُواْ نَٰدِمِينَ ﴾
[الشعراء: 157]
﴿فعقروها فأصبحوا نادمين﴾ [الشعراء: 157]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sì gún un pa. Nítorí náà, wọ́n sì di alábàámọ̀ |