Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 33 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿وَنَزَعَ يَدَهُۥ فَإِذَا هِيَ بَيۡضَآءُ لِلنَّٰظِرِينَ ﴾
[الشعراء: 33]
﴿ونـزع يده فإذا هي بيضاء للناظرين﴾ [الشعراء: 33]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó tún fa ọwọ́ rẹ̀ yọ síta, ó sì di funfun fún àwọn olùwòran |