Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 42 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿قَالَ نَعَمۡ وَإِنَّكُمۡ إِذٗا لَّمِنَ ٱلۡمُقَرَّبِينَ ﴾
[الشعراء: 42]
﴿قال نعم وإنكم إذا لمن المقربين﴾ [الشعراء: 42]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Fir‘aon) wí pé: “Bẹ́ẹ̀ ni, dájúdájú nígbà náà ẹ máa wà nínú àwọn alásùn-únmọ́ (mi).” |