Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 62 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿قَالَ كـَلَّآۖ إِنَّ مَعِيَ رَبِّي سَيَهۡدِينِ ﴾
[الشعراء: 62]
﴿قال كلا إن معي ربي سيهدين﴾ [الشعراء: 62]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì) Mūsā sọ pé: “Rárá, dájúdájú Olúwa mi ń bẹ pẹ̀lú mi. Ó sì máa fi ọ̀nà mọ̀ mí.” |