Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 61 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿فَلَمَّا تَرَٰٓءَا ٱلۡجَمۡعَانِ قَالَ أَصۡحَٰبُ مُوسَىٰٓ إِنَّا لَمُدۡرَكُونَ ﴾
[الشعراء: 61]
﴿فلما تراءى الجمعان قال أصحاب موسى إنا لمدركون﴾ [الشعراء: 61]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí ìjọ méjèèjì ríra wọn, àwọn ìjọ (Ànábì) Mūsā sọ pé: “Dájúdájú wọn yóò lé wa bá.” |