Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 93 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿مِن دُونِ ٱللَّهِ هَلۡ يَنصُرُونَكُمۡ أَوۡ يَنتَصِرُونَ ﴾
[الشعراء: 93]
﴿من دون الله هل ينصرونكم أو ينتصرون﴾ [الشعراء: 93]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (N̄ǹkan tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún) lẹ́yìn Allāhu, ṣé wọ́n lè ràn yín lọ́wọ́ tàbí ṣé wọ́n lè ran ara wọn lọ́wọ́ |