Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 92 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿وَقِيلَ لَهُمۡ أَيۡنَ مَا كُنتُمۡ تَعۡبُدُونَ ﴾
[الشعراء: 92]
﴿وقيل لهم أين ما كنتم تعبدون﴾ [الشعراء: 92]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni wọn yó sì sọ fún wọn pé: “Níbo ni n̄ǹkan tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún wà?” |