Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 13 - النَّمل - Page - Juz 19
﴿فَلَمَّا جَآءَتۡهُمۡ ءَايَٰتُنَا مُبۡصِرَةٗ قَالُواْ هَٰذَا سِحۡرٞ مُّبِينٞ ﴾
[النَّمل: 13]
﴿فلما جاءتهم آياتنا مبصرة قالوا هذا سحر مبين﴾ [النَّمل: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí àwọn àmì Wa, t’ó fojú hàn kedere, sì dé bá wọn, wọ́n wí pé: “Èyí ni idán pọ́nńbélé.” |